Skip to content

السؤال

س16: من أول من آمن برسالته؟

Ibeere 16: Ta ni ẹni akọkọ ti o ni igbagbọ si iranṣẹ rẹ?

الجواب

ج:- من الرجال: أبو بكر الصديق.

  • ومن النساء: خديجة بنت خويلد.
  • ومن الصبيان: علي بن أبي طالب.
  • ومن الموالي: زيد بن حارثة.
  • ومن الأرقاء: بلال الحبشي رَضِيَ اللَّهُ عَنْهُم.

Idahun: Nínú awọn ọkunrin: Abubakr' As-sideeq, ninu awọn obinrin: Khadijah ọmọ Khuwaylid, ninu awọn ọmọ keekeeke: Aliyy ọmọ Abuu Taalib, ninu awọn ẹru ti o ti di ọmọ: Zaid ọmọ Haaritha, ninu awọn ẹru: Bilaal Al-Habashiy (ki Ọlọhun yọnu si wọn) ati awọn miiran.