Skip to content

Bawo ni ìṣesí rẹ ṣíwájú Wahyi (Imisi)? Àti pé ìgbà wo ni Wahyi sọkalẹ fun un ni igba akọkọ?

الباب / الفصل
قسم السيرة النبوية

السؤال

س14: كيف كان حاله قبل الوحي؟ ومتى نزل عليه الوحي أول مرة؟

Ibeere 14: Bawo ni ìṣesí rẹ ṣíwájú Wahyi (Imisi)? Àti pé ìgbà wo ni Wahyi sọkalẹ fun un ni igba akọkọ?

الجواب

ج:كان يتعبد لله في غار حراء ويتزود لذلك.

ونزل عليه الوحي، وهو في الغار يتعبد.

Idahun- O jẹ ẹni tí maa n ṣe ijọsin fun Ọlọhun ninu kòtò Hirā ti o si maa mú èsè dání fun un.

Wahyi (imisi) si sọkalẹ fun un, nígbà tí o wa nínú koto naa ni ẹni ti n ṣe ijọsin.