Skip to content

"Ibeere kẹta: Ki ni ọla ti o wa fun aluwala? "

الباب / الفصل
قسم الفقه

السؤال

س3: ما هو فضل الوضوء؟

"Ibeere kẹta: Ki ni ọla ti o wa fun aluwala? "

الجواب

ج:قال النبي عَلَيْهِ الصَّلَاةُ وَالسَّلَامُ:

«إذا توضأ العبد المسلم -أو المؤمن- فغسل وجهه؛ خرج من وجهه كل خطيئةٍ نظر إليها بعينيه مع الماء - أو مع آخر قطر الماء - فإذا غسل يديه؛ خرج من يديه كل خطيئة كان بطشتها يداه مع الماء -أو مع آخر قطر الماء - فإذا غسل رجليه؛ خرجت كل خطيئة مشتها رجلاه مع الماء -أو مع آخر قطر الماء- حتى يخرج نقيَّا من الذنوب»

رواه مسلم.

"Anabi -ki ikẹ ati ọla maa ba a- sọ pe:

“Ti musulumi ba ṣe aluwala, tabi olugbagbọ, ti o wa fọ oju rẹ; gbogbo ẹṣẹ ti o fi oju rẹ wo a jade pọ mọ omi, tabi pẹlu ekikan omi to kẹyin, ti o ba fọ ọwọ rẹ mejeeji; gbogbo ẹṣẹ ti o fi ọwọ rẹ mejeeji gbamu a jade pọ mọ omi, tabi pẹlu ekikan omi to kẹyin, ti o ba fọ ẹsẹ rẹ mejeeji; gbogbo ẹṣẹ ti o fi ẹsẹ rẹ mejeeji rin lọ sibẹ a jade pọ mọ omi, tabi pẹlu ekikan omi to kẹyin, titi yoo fi jade ni ẹni ti o mọ kuro nibi awọn ẹṣẹ”

Muslim ni o gba a wa.