Ki ni a n pe ni adadaalẹ? Ati pe ṣe a maa gba a?
- الموضوعات
- التوحيد وحمايتهالبدعة
- التصنيف الشرعي
- العقيدةالبدعةحقيقة البدعة
- الباب / الفصل
- قسم العقيدة
السؤال
Ibeere 18: Ki ni a n pe ni adadaalẹ? Ati pe ṣe a maa gba a?
س18: ما هي البدعة؟ وهل نقبلها؟
الجواب
Idahun- Gbogbo nkan ti awọn eeyan ba daalẹ sinu ẹsin, ti ko si si nigba aye Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - ati awọn saabe rẹ.
A o nii gba a, ati pe a maa da a pada ni.
Fun ọrọ Anabi - ki ikẹ ati ọla maa ba a - pe:
Gbogbo adadaalẹ pata anu ni
Abu Daud ni o gba a wa.
Apejuwe rẹ: Alekun nibi ijọsin, gẹ́gẹ́ bíi ṣiṣe alekun fifọ ẹlẹẹkẹrin nibi aluwala, ati ṣiṣe ayẹyẹ ọjọ-ibi Anabi, ko wa lati ọdọ Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - ati awọn saabe rẹ.
ج:كل ما أحدثه الناس في الدين، ولم يكن على عهد النبي صلى الله عليه وسلم وأصحابه.
- لا نقبلها، ويجب أن نردها.
لقول النبي عَلَيْهِ الصَّلَاةُ وَالسَّلَامُ:
«كل بدعة ضلالة»
رواه أبو داود.
- وقوله عليه الصلاة والسلام:
«من عمل عملًا ليس عليه أمرنا فهو رد»
رواه مسلم.
مثالها: الزيادة في العبادة، كالزيادة على الوضوء غسلة رابعة، وكالاحتفال بالمولد النبوي، فلم يرد عن النبي صلى الله عليه وسلم وأصحابه.