Skip to content

"Ibeere ẹlẹẹkejila: Ki ni nnkan to jẹ dandan lati ṣe nigba ti o ba ri obinrin kan to jẹ ajoji? "

الباب / الفصل
قسم المنوعات

السؤال

س۱۳: ما الواجب إذا رأيت امرأة أجنبية؟

"Ibeere ẹlẹẹkejila: Ki ni nnkan to jẹ dandan lati ṣe nigba ti o ba ri obinrin kan to jẹ ajoji? "

الجواب

ج:الواجب غض البصر،

قال تَعَالَى:

﴿قُلْ لِلْمُؤْمِنِينَ يَغُضُّوا مِنْ أَبْصَارِهِمْ﴾

[النور: ٣٠].

"Idahun- Nǹkan to jẹ dandan ni rirẹ oju nilẹ, Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe: "

"{Sọ fún àwọn onígbàgbọ́ òdodo lọ́kùnrin pé kí wọ́n rẹ ojú wọn nílẹ̀}

"[Surah An-Nûr: 30]"