Skip to content

Bawo ni Anabi (ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a) ṣe n pe awọn eeyan ni ita Makkah?

الباب / الفصل
قسم السيرة النبوية

السؤال

س21: كيف كان النبي صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ يدعو الناس خارج مكة؟

Idahun 21: Bawo ni Anabi (ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a) ṣe n pe awọn eeyan ni ita makkah?

الجواب

ج:كان يدعو أهل الطائف، ويعرض نفسه في المواسم ومجامع الناس، حتى جاء أهل المدينة من الأنصار، فآمنوا بالنبي صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ، وبايعوه على نصرته.

Idahun: O maa n ṣe ipepe fun awọn ara ilẹ Taaif, o si maa n fi ara rẹ han wọn ni àwọn aaye ipadepọ awọn eeyan titi ti awọn Ansọọr fi de lati ilu Mẹdina ti wọn si gba a gbọ, wọn si tun gba ọwọ rẹ ni ti adehun lati ran an lọ́wọ́.