Skip to content

Igba melo ni Anabi (ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a) fi wa ni Mẹka ti n pe awọn eeyan?

الباب / الفصل
قسم السيرة النبوية

السؤال

س22: كم بقي النبي صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ في مكة يدعو؟

Ibeere 22: Igba melo ni Anabi (ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a) fi wa ni Mẹka ti n pe awọn eeyan?

الجواب

ج:بقي ثلاث عشرة سنة.

Idahun- O lo ọdun mẹtala nibẹ.