Skip to content

السؤال

س38: عرف الصيام؟

Ibeere kẹtadinlọgbọn: Sọ itumọ Aawẹ gbigba?

الجواب

ج:هو التعبد لله بالإمساك عن المفطرات من طلوع الفجر إلى غروب الشمس، مع النية، وهو نوعان:

  1. صيام واجب: مثل صيام شهر رمضان، وهو ركن من أركان الإسلام.

قال تَعَالَى:

﴿يَٰٓأَيُّهَا ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ كُتِبَ عَلَيۡكُمُ ٱلصِّيَامُ كَمَا كُتِبَ عَلَى ٱلَّذِينَ مِن قَبۡلِكُمۡ لَعَلَّكُمۡ تَتَّقُونَ﴾

[البقرة: 183].

2. وصيام غير واجب: مثل صوم الإثنين والخميس من كل أسبوع، وصيام ثلاثة أيام من كل شهر، وأفضلها أيام البيض (13، 14، 15) من كل شهر قمري.

Idahun: Oun ni ṣiṣe ijọsin fun Ọlọhun pẹlu kikoraro kuro nibi ohun ti o le ba aawẹ jẹ lati igba ti alufajari ba ti yọ titi di igba ti oorun yoo fi wọ pẹlu dida aniyan, o si ni iran meji:

Aawẹ ọranyan: Bii gbigba aawẹ oṣu Ramadan, o si jẹ origun kan ninu awọn origun Isilaamu.

Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe:

Ẹ̀yin tí ẹ gbàgbọ́ ní òdodo, A ṣe ààwẹ̀ náà ní ọ̀ran-anyàn fun yín, gẹ́gẹ́ bí A ti ṣe é ní ọ̀ran-anyàn fún àwọn t’ó ṣíwájú yín, nítorí kí ẹ lè bẹ̀rù (Allāhu). 183

[Suuratul-Baqarah: 24].

Aawẹ ti kii ṣe ọranyan: Gẹ́gẹ́ bii gbigba aawẹ ọjọ aje ati ọjọbọ ni gbogbo ọsẹ, ati gbigba aawẹ ọjọ mẹta ni gbogbo oṣu, awọn ọjọ ti o si lọla ju ninu rẹ naa ni (13, 14, 15) ni gbogbo oṣu oju ọrun.