Skip to content

السؤال

س32: هل يجوز التخلف عن صلاة الجمعة؟

Ibeere 31: Njẹ o lẹ́tọ̀ọ́ lati má ki irun Jimọh bi?

الجواب

ج:لا يجوز التخلف عن صلاة الجمعة إلا من عذر شرعي، وجاء عن النبي ﷺ، قوله:

«من ترك ثلاث جمع تهاونًا بها؛ طبع الله على قلبه»

رواه أبو داود وغيره.

"Idahun- Pipa irun ọjọ jimọh jẹ o lẹ́tọ̀ọ́ afi pẹlu idi kan to jẹ ti sharia, o wa lati ọdọ Anabi -ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- pe: "

“Ẹnikẹni ti o ba gbe irun ọjọ jimọh mẹta ju silẹ ni ti ailakakun pẹlu ẹ; Ọlọhun maa fi edidi di ọkan rẹ”. "

Abu Daūd ati ẹlomiran yatọ si i ni wọ́n gba a wa.