Skip to content

السؤال

س35: ما هو الخشوع في الصلاة؟

"Ibeere ẹlẹẹkẹrinlelọgbọn: Ki ni irẹlẹ nibi irun? "

الجواب

ج:هو حضور القلب وسكون الجوارح فيها.

قال تَعَالَى:

﴿قَدۡ أَفۡلَحَ ٱلۡمُؤۡمِنُونَ 1

ٱلَّذِينَ هُمۡ فِي صَلَاتِهِمۡ خَٰشِعُونَ 2﴾

[المؤمنون: 1-2].

"Idahun- oun ni ki ọkàn wà nibẹ, ki ara o sì balẹ.

Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe:

{Dájúdájú àwọn onígbàgbọ́ òdodo ti jèrè 1 "

"{Àwọn t’ó ń páyà (Allāhu) nínú ìrun wọn 2}

"[Surah Al-Mu’minûn: 1, 2]"