Skip to content

السؤال

س31: كم عدد ركعات صلاة الجمعة؟

Ibeere 30: Meloo ni onka Raka‘a Irun Jumu‘a?

الجواب

ج:عدد ركعات صلاة الجمعة ركعتان يجهر فيهما الإمام بالقراءة، حيثُ تتقدّمهما خطبتان معروفتان.

Idahun- Onka Raka‘a Irun Jumu‘a meji ni, ti Imāmu o si gbe ohun s'oke nibẹ, l'eyi ti o ṣe wipe khutubah meji ti a ti mọ o ṣaaju rẹ.