Skip to content
Awọn iṣẹ ijọsin Hajj

Awọn iṣẹ ijọsin Hajj

Ìwé pélébé tó ṣe àlàyé ní ṣókí lórí àwọn iṣẹ́ ìjọsìn Hajj, bẹ̀rẹ̀ láti gbígbé harami ní ọjọ́ kẹjọ, títí kan àwọn iṣẹ́ ọjọ́ Arafa, ṣíṣe àwọn iṣẹ́ ìjọsìn ọjọ́ ọdún, àti jijú òkúta Jamarat, títí dé tawaafu ( irọkirika ile Ọlọhun) Ifaada àti tawaafu Wadaa (Irọkirika ilé Ọlọhun ti idagbere).

Èdè: lang_yo
Ẹni tí ó pèsè: Muhammad ọmọ Solih Al-Uthaymīn
Ẹ̀yà: 1.0
Download PDF 188 KB

This PDF is generated automatically from the book's text; its layout may differ from the printed edition.

0%
Font size