Skip to content
Àkójọ Àwọn Súrà /

المُطَففين

المُطَففين is chapter 83 of the Quran and has 36 verses. This page presents it in full in the Uthmani script, with a verse-by-verse translation of its meaning.

36 Àwọn Ẹsẹ Nọ́ńbà Súrà 83
Lọ sí ẹsẹ
Yorùbá · Mikail
بِسْمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحْمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ

وَيۡلٞ لِّلۡمُطَفِّفِينَ

Ègbé ni fún àwọn olùdín-òṣùwọ̀n-kù,

ٱلَّذِينَ إِذَا ٱكۡتَالُواْ عَلَى ٱلنَّاسِ يَسۡتَوۡفُونَ

àwọn (òǹtajà) tó jẹ́ pé nígbà tí wọ́n bá wọn n̄ǹkan lọ́dọ̀ àwọn ènìyàn, wọ́n á gbà á ní ẹ̀kún,

Explanation & meanings · 1
  1. “Àwọn ènìyàn” ní àyè yìí dúró fún bíi “ àwọn olóko”.

وَإِذَا كَالُوهُمۡ أَو وَّزَنُوهُمۡ يُخۡسِرُونَ

nígbà tí àwọn (òǹtajà náà) bá sì lo ìwọ̀n fún àwọn (òǹrajà) tàbí lo òṣùwọ̀n fún wọn, wọn yóò dín in kù.

أَلَا يَظُنُّ أُوْلَٰٓئِكَ أَنَّهُم مَّبۡعُوثُونَ

Ṣé àwọn wọ̀nyẹn kò mọ̀ dájú pé dájúdájú A máa gbé wọn dìde

لِيَوۡمٍ عَظِيمٖ

ní Ọjọ́ ńlá kan?