Skip to content
Al-Mutoffifiin /

Ẹsẹ 32

83 : 32

Ẹsẹ 32 of Al-Mutoffifiin (83 : 32). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

Al-Mutoffifiin Àwọn Ẹsẹ 36
Súrà · Al-Mutoffifiin
Yorùbá · Mikail
83 : 32

وَإِذَا رَأَوۡهُمۡ قَالُوٓاْ إِنَّ هَٰٓؤُلَآءِ لَضَآلُّونَ

Àti pé nígbà tí wọ́n bá rí (àwọn onígbàgbọ́ òdodo) wọ́n á wí pé: “Dájúdájú àwọn wọ̀nyí ni olùṣìnà.”