Skip to content

Kí ni iṣesi Anabi (ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a) ati awọn ti wọn gba a gbọ wa lẹyin ti ipepe gbangba waye?

الباب / الفصل
قسم السيرة النبوية

السؤال

س18: ما كان حال النبي صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ ومن آمن به بعد الجهر بالدعوة؟

Ibeere 18: Kí ni iṣesi Anabi (ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a) ati awọn ti wọn gba a gbọ wa lẹyin ti ipepe gbangba waye?

الجواب

ج:بالغ المشركون في أذيته وأذية المسلمين، حتى أذن للمؤمنين بالهجرة إلى النجاشي في الحبشة.

وأجمع أهل الشرك على أذية وقتل النبي صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ، فحماه الله وأحاطه بعمه أبو طالب ليحميه منهم.

Idahun– Àwọn ọṣẹbọ fi ṣuta kan an gan ati awọn Musulumi, titi ti o fi yọnda fun awọn olugbagbọ ododo lati ṣe hijira lọ si ọdọ Najaashi ni ilẹ Habasha.

Awọn ẹlẹbọ si fi ẹnu kò lati fi ṣuta kan an, ati lati pa a (ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a). Ọlọhun wa dáàbò bo o, ti O si rọgbayika rẹ pẹlu ẹgbọn baba rẹ tii ṣe Abuu Taalib lati le baa daabo bo o kuro lọwọ wọn.