Skip to content

السؤال

س١9: ما حكم ترك الصلاة؟

Ibeere 18: Ki ni idajọ gbigbe Irun ju silẹ?

الجواب

ج:ترك الصلاة كفر،

قال النبي عَلَيْهِ الصَّلَاةُ وَالسَّلَامُ:

«العهد الذي بيننا وبينهم الصلاة، فمن تركها فقد كفر»

رواه أحمد والترمذي وغيرهما.

Idahun- Gbigbe Irun ju silẹ iṣe aìgbàgbọ́ ni, Anabi- kí ikẹ ati ọla maa ba a- sọ pe:

Idahun- Gbigbe Irun ju silẹ iṣe aìgbàgbọ́ ni, Anabi- kí ikẹ ati ọla maa ba a- sọ pe: «Adehun ti n bẹ laarin wa ati laaarin wọn (awọn alaigbagbọ) ni Irun, ẹniti o ba wa gbe Irun ju silẹ ti di alaigbagbọ». Ahmad ati Tirimidhi ati awọn mii yatọ si awọn mejeeji ni wọ́n gba a wa.

Adehun ti n bẹ laarin wa ati laaarin wọn (awọn alaigbagbọ) ni Irun