Skip to content

Irun mélòó lo jẹ dandan lori Musulumi ni ojumọ (aarọ ati alẹ)? Melo si ni awọn onka Irun kọọkan?

الموضوعات
الصلاة
الباب / الفصل
قسم الفقه

السؤال

س20: کم صلاة تجب على المسلم في اليوم والليلة؟ وكم عدد رکعات كل صلاة؟

Ibeere 19- Irun mélòó lo jẹ dandan lori Musulumi ni ojumọ (aarọ ati alẹ)? Melo si ni awọn onka Irun kọọkan?

الجواب

ج:خمس صلوات في اليوم والليلة.

  • صلاة الفجر: ركعتان.
  • وصلاة الظهر: أربع ركعات.
  • وصلاة العصر: أربع ركعات.
  • وصلاة المغرب: ثلاث ركعات.
  • وصلاة العشاء: أربع ركعات.

Idahun- Irun márùn-ún ni ni ojumọ (aarọ ati alẹ), Irun Al-fajri: Rakah meji, Irun Dhuri: Rakah mẹẹrin, Irun Asri: Rakah mẹẹrin, Irun Magrib: Rakah mẹta, Irun Ishai: Rakah mẹẹrin.