Skip to content

"Ibeere karun-un: Ki ni awọn ọranyan aluwala, ati onka wọn? "

الباب / الفصل
قسم الفقه

السؤال

س5: ما هي فرائض الوضوء، وعددها؟

"Ibeere karun-un: Ki ni awọn ọranyan aluwala, ati onka wọn? "

الجواب

ج:هي التي لا يصح وضوء المسلم إذا ترك واحدة منها.

  1. غسل الوجه، ومنه المضمضة والاستنشاق.
  2. غسل اليدين إلى المرفقين.
  3. مسح الرأس ومنه الأذنين.
  4. غسل الرجلين إلى الكعبين.
  5. الترتيب بين الأعضاء، بأن يغسل الوجه، ثم اليدين، ثم مسح الرأس، ثم غسل الرجلين.

قال تعالى:

﴿يَٰٓأَيُّهَا ٱلَّذِينَ ءَامَنُوٓاْ إِذَا قُمۡتُمۡ إِلَى ٱلصَّلَوٰةِ فَٱغۡسِلُواْ وُجُوهَكُمۡ وَأَيۡدِيَكُمۡ إِلَى ٱلۡمَرَافِقِ وَٱمۡسَحُواْ بِرُءُوسِكُمۡ وَأَرۡجُلَكُمۡ إِلَى ٱلۡكَعۡبَيۡنِۚ﴾

[المائدة: ٦].

  1. الموالاة: وهي الوضوء في وقت متواصل، دون فاصل من الوقت حتى تجف الأعضاء من الماء.

كأن يتوضأ نصف وضوء، ويكمل في وقت آخر، فلا يصح وضُوؤُه.

لحديث:

«أن النبي صلى الله عليه وسلم رأى رجلًا يصلي وفي ظهر قدمه لمعة قدر الدرهم، لم يصبها الماء، فأمره النبي صلى الله عليه وسلم أن يعيد الوضوء والصلاة»

رواه أبو داود.

"Idahun- Oun ni eyi ti aluwala musulumi ko nii ni alaafia ti o ba gbe ẹyọkan ju silẹ ninu ẹ. "

"1- Fifọ oju ti yiyọ ẹnu ati fifa omi si imu n bẹ ninu ẹ. "

"2- Fifọ ọwọ mejeeji titi de igunpa mejeeji. "

"3- Pipa ori ti eti mejeeji n bẹ ninu ẹ

"4- Fifọ ẹsẹ mejeeji titi de kokosẹ mejeeji. "

"5- Ìtòlẹ́sẹẹsẹ laarin awọn oríkèé, pẹlu pe ki o fọ oju, lẹyin naa ọwọ mejeeji, lẹyin naa pipa ori, lẹyin naa fifọ ẹsẹ mejeeji. "

"6- Itẹsiwaju: Oun ni ṣíṣe aluwala ní ọ̀nà tí kò dáwọ́ dúró, láìsí ìsinmi kankan ní àkókò tí yóò jẹ́ kí àwọn ẹ̀yà ara gbẹ kúrò nínú omi."

"7- Gẹgẹ bii ki o ṣe idaji aluwala, ki o wa pari ẹ ni asiko miiran, aluwala rẹ o ni alaafia."