Skip to content

"Ibeere ẹlẹẹkẹtala: Ǹjẹ́ ẹnikankan yatọ si Ọlọhun -ti ọla Rẹ ga- ni imọ ikọkọ? "

الباب / الفصل
قسم العقيدة

السؤال

"Ibeere ẹlẹẹkẹtala: Ǹjẹ́ ẹnikankan yatọ si Ọlọhun -ti ọla Rẹ ga- ni imọ ikọkọ? "

س13: هل يعلم الغيب أحد سوى الله تَعَالَى؟

الجواب

"Idahun- ẹnikankan o ni imọ ikọkọ afi Ọlọhun nikan ṣoṣo. "

Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe:

"{Sọ pé: “Àwọn t’ó wà nínú àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀ kò nímọ̀ ìkọ̀kọ̀ àfi Allāhu. Àti pé wọn kò sì mọ àsìkò wo ni A máa gbé àwọn òkú dìde 65} "

"[Suuratun Naml: 65]"

ج:لا يعلم الغيب إلا الله وحده.

قال تَعَالَى:

﴿قُل لَّا يَعۡلَمُ مَن فِي ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِ ٱلۡغَيۡبَ إِلَّا ٱللَّهُۚ وَمَا يَشۡعُرُونَ أَيَّانَ يُبۡعَثُونَ﴾

[النمل: 65].