Skip to content

"Ibeere ẹlẹẹkọọkanla: Ki ni ẹṣẹ ti o tobi julọ? "

الباب / الفصل
قسم العقيدة

السؤال

"Ibeere ẹlẹẹkọọkanla: Ki ni ẹṣẹ ti o tobi julọ? "

س11: ما أعظم ذنب؟

الجواب

"Idahun- mimu orogun pẹlu Ọlọhun ti ọla Rẹ ga”

Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe:

"{Dájúdájú Allāhu kò níí foríjin (ẹni tí) ó bá ń ṣẹbọ sí I. Ó sì máa ṣàforíjìn fún ohun mìíràn yàtọ̀ sí ìyẹn fún ẹni tí Ó bá fẹ́. Ẹni tí ó bá ń ṣẹbọ sí Allāhu, dájúdájú ó ti dá àdápa irọ́ (tí ó jẹ́) ẹ̀ṣẹ̀ ńlá 48}"

"[Surah An-Nisâ': 48]"

ج:الشرك بالله تَعَالَى.

قال تَعَالَى:

﴿إِنَّ ٱللَّهَ لَا يَغۡفِرُ أَن يُشۡرَكَ بِهِۦ وَيَغۡفِرُ مَا دُونَ ذَٰلِكَ لِمَن يَشَآءُۚ وَمَن يُشۡرِكۡ بِٱللَّهِ فَقَدِ ٱفۡتَرَىٰٓ إِثۡمًا عَظِيمًا﴾

[النساء: 48]