Skip to content

"Ibeere ẹlẹẹkeji: ki ni ẹsin rẹ? "

الباب / الفصل
قسم العقيدة

السؤال

"Ibeere ẹlẹẹkeji: ki ni ẹsin rẹ? "

س2: ما دينك؟

الجواب

"Idahun- Ẹsin mi ni Isilaamu, oun ni: Jijupa-jusẹ silẹ fun Ọlọhun pẹlu igbagbọ ninu Ẹ ni Oun nikan ṣoṣo, ati itẹriba fun Un pẹlu itẹle, ati mimọ kuro nibi ẹbọ ati awọn ẹlẹbọ. "

Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe:

Dájúdájú ẹ̀sìn t’ó wà lọ́dọ̀ Allāhu ni ’Islām.

[Surah Âl-`Imrân: 19]"

ج:ديني الإسلام، وهو: الاستسلام لله بالتوحيد، والانقياد له بالطاعة، والبراءة من الشرك وأهله.

قال تَعَالَى:

﴿إِنَّ ٱلدِّينَ عِندَ ٱللَّهِ ٱلۡإِسۡلَٰمُۗ﴾

[آل عمران: 19].