Skip to content

Dajudaju Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ṣe aluwala lẹẹmeji meji.

Lati ọdọ Abdullahi ọmọ Zaid- ki Ọlọhun yọnu si i-:

Dajudaju Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ṣe aluwala lẹẹmeji meji.

أَنَّ النَّبِيَّ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ تَوَضَّأَ مَرَّتَيْنِ مَرَّتَيْنِ.

Bukhaariy lọ gba a wa
O ni alaafia
Àlàyé

Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- nigba mii ti o ba fẹ ṣe aluwala, o maa n fọ gbogbo orikee ninu awọn orikee aluwala lẹẹmeji, o maa fọ oju- ti gbigbo ẹnu ati fifa omi simu n bẹ nibẹ- ati ọwọ mejeeji ati ẹsẹ mejeeji lẹẹmeji.

Ìtumọ̀ àwọn gbólóhùn

...:

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

Eyi ti o jẹ dandan ni fifọ awọn orikee lẹẹkan ati pe eyi ti o ba lekun jẹ nnkan ti a fẹ.

Ṣíṣe lofin ṣíṣe aluwala lẹẹmeji meji nigba mii.

Nnkan ti a ṣe lofin nibi pipa ori ni ẹẹkan.

Àwọn ìwé ìwádìí

Tira Sọhiihu ti Bukhaariy (1/ 43) (158).

Àlékún (1)

إرشاد الساري لشرح صحيح البخاري (1/ 244).