Skip to content

السؤال

س30: من أولاده صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ؟

Ibeere 30: Awọn wo ni awọn ọmọ rẹ (ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a)?

الجواب

ج:من الذكور ثلاثة:

  • القاسم، وبه كان يكنى.
  • وعبد الله.
  • وإبراهيم.
  • من الإناث:
  • فاطمة.
  • رقية.
  • أم كلثوم.
  • زينب.

وكل ولده من خديجة رَضِيَ اللَّهُ عَنْهَا، إلا إبراهيم من مارية القبطية، وكلهم مات قبله إلا فاطمة بعده بستة أشهر.

Awọn ọkunrin mẹta ni wọn:

Qāsim, oun si ni wọn fi maa n da a pe.

Ati Abdullāhi.

Ati Ibrāhīm.

Awọn Obinrin:

Fatima

Rukayyah

Ummu kulthuum

Zaynab

Gbogbo ọmọ rẹ pata, ati ara Khadījah ni wọn ti wa- ki Ọlọhun yọnu si i- ayaafi Ibrāhīm, gbogbo wọn lo si ku ṣaaju rẹ ayaafi Fātimah to ku lẹyin rẹ lẹyin oṣu mẹfa.