Skip to content

"Ibeere ẹlẹẹkẹtadinlọgbọn: ki ni eyi to kẹyin ninu nnkan ti wọn sọkalẹ ninu Kuraani? "

الباب / الفصل
قسم السيرة النبوية

السؤال

س27: ما آخر ما نزل من القرآن؟

"Ibeere ẹlẹẹkẹtadinlọgbọn: ki ni eyi to kẹyin ninu nnkan ti wọn sọkalẹ ninu Kuraani? "

الجواب

ج:قوله تَعَالَى:

﴿وَٱتَّقُواْ يَوۡمٗا تُرۡجَعُونَ فِيهِ إِلَى ٱللَّهِۖ ثُمَّ تُوَفَّىٰ كُلُّ نَفۡسٖ مَّا كَسَبَتۡ وَهُمۡ لَا يُظۡلَمُونَ﴾

[البقرة: 281].

Idahun- Gbolohun Ọba- ti ọla Rẹ ga- pe:

"{Ẹ bẹ̀rù ọjọ́ kan tí wọ́n máa da yín padà sí ọ̀dọ̀ Allāhu. Lẹ́yìn náà, Wọ́n máa san ẹ̀mí kọ̀ọ̀kan ní ẹ̀san ní ẹ̀kún rẹ́rẹ́ (nípa) ohun tí ó ṣe níṣẹ́. Wọn kò sì níí ṣàbòsí sí wọn 281}. "

[Suuratul-Baqarah: 24].