Skip to content

Obinrin kan de ni ẹni ti o gbe áràmí Umrah, lẹyin dide rẹ si Makkah ni o ba ri nnkan oṣu, eleewọ rẹ si gbọdọ̀ ṣe ìrìn-àjò ni kiakia, ti ko si ni ẹni kankan ni Makkah, ki ni idajọ naa?

السؤال

Ibeere akọkọ:

Obinrin kan de ni ẹni ti o gbe áràmí Umrah, lẹyin dide rẹ si Makkah ni o ba ri nnkan oṣu, eleewọ rẹ si gbọdọ̀ ṣe ìrìn-àjò ni kiakia, ti ko si ni ẹni kankan ni Makkah, ki ni idajọ naa?

س49: قدمت امرأةٌ محرمةً بعمرةٍ، وبعد وصولها إلى مكة حاضت، ومحرمها مضطرٌّ إلى السفر فورًا، وليس لها أحدٌ بمكة، فما الحكم؟

الجواب

Idahun akọkọ:

Yoo ṣe ìrìn-àjò pẹlu rẹ, ti yoo si wa lori arami rẹ, lẹyin naa yoo ṣeri pada ti o ba ti mọ, eyi o maa ri bẹ́ẹ̀ ti o ba wa ni Saudi; nitori pe ṣiṣẹri pada rọrun, ko si bukaata si idamu kankan, tabi si ìwé ìrìnnà ati nnkan ti o jọ ọ.

Ṣugbọn ti o ba jẹ ajoji, ti ṣiṣẹri pada nira fun un, yoo wé nǹkan mọ́ ojú ara rẹ, yoo si rọkirika ile Oluwa, yoo sa safa ati mariwa, yoo ge irun rẹ, yoo si pari Umrah rẹ ni ìrìn-àjò kan naa, nitori pe irọkirika ile Oluwa rẹ nigba naa ti di kò-ṣeé-má-ṣe, kò-ṣeé-má-ṣe si maa n sọ nnkan eewọ di ẹtọ ni.

ﺟ49: تسافر معه، وتبقى على إحرامها، ثم ترجع إذا طهرت، وهذا إذا كانت في المملكة؛ لأن الرّجوع سهلٌ، ولا يحتاج إلى تعبٍ، ولا إلى جواز سفرٍ ونحوه.

أمّا إذا كانت أجنبيةً، ويشقّ عليها الرّجوع، فإنها تتحفظ، وتطوف، وتسعى، وتقصّر، وتنهي عمرتها في نفس السفر؛ لأن طوافها حينئذٍ صار ضرورةً، والضرورة تبيح المحظور.