Skip to content

Ki ni waa sọ ti o ba fẹ dìde nígbà ti o ba ṣetan ni ijokoo "Adua ipa aṣiṣe ijokoo rẹ (kaffāratul Majlis)"?"

الباب / الفصل
قسم الأدعية والأذكار

السؤال

س٢٥: ما تقول عند القيام والفراغ من المجلس "دعاء كفارة المجلس"؟

"Ibeere 25: Ki ni waa sọ ti o ba fẹ dìde nígbà ti o ba ṣetan ni ijokoo "Adua ipa aṣiṣe ijokoo rẹ (kaffāratul Majlis)"?"

الجواب

ج:«سبحانك اللهم وبحمدك، أشهد أن لا إله إلا أنت، أستغفرك وأتوب إليك»

رواه أبو داود والترمذي وغيرهما.

"Idahun- «SubhānaKa Allāhummọ wa bi hamdiKa, ash’hadu an lā ilāha illā Anta, astagfiruKa wa atūbu ’illayKa» "

"Abū Dāud ati Tirmidhiy ati ẹlomiran yatọ si awọn mejeeji ni wọ́n gba a wa."