Skip to content

السؤال

س10: متى كان سفره الثاني؟

Ibeere 10: Ìgbà wo ni irin-ajo rẹ eleekeji wáyé?

الجواب

ج:كان سفره الثاني في تجارة بمال خديجة رَضِيَ اللَّهُ عَنْهَا، ولمَّا رجع تزوجها صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ، وله من العمر خمس وعشرون سنة.

Idahun- Irin-ajo rẹ ẹlẹẹkeji wáyé nipa òwò kan ti o ṣe pẹlu owó Khadījah- ki Ọlọhun yọnu si i-, nígbà tí o wa ṣẹri pada, o- ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a- wa fẹ ẹ (Khadījah).