Skip to content

"Ibeere ẹlẹẹkẹtadinlogoji: Ǹjẹ́ igbagbọ a maa lekun a si tun maa dínkù? "

الموضوعات
الإيمان
التصنيف الشرعي
العقيدةالإيمان
الباب / الفصل
قسم العقيدة

السؤال

س37: هل الإيمان يزيد وينقص؟

"Ibeere ẹlẹẹkẹtadinlogoji: Ǹjẹ́ igbagbọ a maa lekun a si tun maa dínkù? "

الجواب

ج:الإيمان يزيد بالطاعة وينقص بالمعصية.

  • قال تَعَالَى:

﴿إِنَّمَا ٱلۡمُؤۡمِنُونَ ٱلَّذِينَ إِذَا ذُكِرَ ٱللَّهُ وَجِلَتۡ قُلُوبُهُمۡ وَإِذَا تُلِيَتۡ عَلَيۡهِمۡ ءَايَٰتُهُۥ زَادَتۡهُمۡ إِيمَٰنٗا وَعَلَىٰ رَبِّهِمۡ يَتَوَكَّلُونَ﴾

[الأنفال: 2].

"Idahun- igbagbọ maa n lekun pẹlu itẹle a si maa dínkù pẹlu ẹṣẹ. "

Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe:

"{Àwọn onígbàgbọ́ òdodo ni àwọn t’ó jẹ́ pé nígbà tí wọ́n bá fi (ìyà) Allāhu ṣe ìrántí (fún wọn), ọkàn wọn yóò wárìrì, nígbà tí wọ́n bá sì ké àwọn āyah Rẹ̀ fún wọn, wọn yóò lékún ní ìgbàgbọ́ òdodo. Olúwa wọn sì ni wọ́n ń gbáralé 2} "

"[Surah Al-Anfâl: 2]"