«Bẹrù Ọlọhun ní ibikibi tí o ba wa, tẹ̀lé ìṣe búburú pẹ̀lú ìṣe rere, yóò pa á rẹ́; máa ba awọn ènìyàn lo pẹlu ìwà daada».
Láti ọdọ Abu Dhari, tii ṣe Jundub ọmọ Junaadah, àti Abu Abdir-Rahman, tii ṣe Mu'ahdh ọmọ Jabal kí Ọlọhun yọnu sí awọn méjèjì, láti ọdọ òjíṣẹ Ọlọhun kí ikẹ Ọlọhun àti ọla Rẹ o máa ba a, o sọ pé:
«Bẹrù Ọlọhun ní ibikibi tí o ba wa, tẹ̀lé ìṣe búburú pẹ̀lú ìṣe rere, yóò pa á rẹ́; máa ba awọn ènìyàn lo pẹlu ìwà daada».
«اتَّقِ اللَّهَ حَيْثُمَا كُنْت، وَأَتْبِعْ السَّيِّئَةَ الْحَسَنَةَ تَمْحُهَا، وَخَالِقْ النَّاسَ بِخُلُقٍ حَسَنٍ».
Annabi kí ikẹ Ọlọhun àti ọlá Rẹ o máa ba npa wa lasẹ nkan mẹta ọtọtọ: Alakọkọ: ìbẹ̀rù Ọlọhun pẹlu pé kí a máa ṣe awọn nkan tí o jẹ ọranyan, àti gbígbé awọn nkan tí o jẹ èèwọ jù silẹ ní gbogbo ààyè àti àsìko àti ìṣesí, ní kọkọ àti ni gbangba, ni gbàá Alaafia àti àdánwò àti bẹ bẹ lọ. Ẹlẹẹkeji: tí o ba bọ sínú àìda kan, yaa ṣe iṣe daada kan lẹyìn rẹ; gẹgẹ bi kí ọ kirun, àti itọrẹ aanu, iṣe daada sí òbí àti iso òkun ẹbi pọ, àti itọrọ aforiji ẹsẹ -tàbí isiwọ kúrò níbi ẹsẹ- àti bẹ bẹ lọ, nitoripe dájúdájú eléyun yiò pàá àìda rẹ. Ẹlẹẹkẹta: Baa awọn ènìyàn lo pẹlu awọn iwā daada, bíi irẹrin musẹ sí wọn tàbí itujuka, àti ise pẹlẹ pẹlu wọn, àti rirọ pẹlu wọn, ati sise daada si wọn àti ikora dúró níbi fífi aburú kan wọn.
Oore-ọfẹ Ọlọhun - tí O Gbọngbọn tí O Tóbi- lori awọn ẹrú nípa ikẹ rẹ, ati aforiji rẹ́, àti amojukuro rẹ.
Hadith náà kó awọn iwọ mẹta sínú: iwọ Ọlọhun l'atari ìbẹrù Rẹ, àti iwọ ẹmi ará ẹni l'atari ṣíṣe iṣẹ rere lẹyin aida, àti iwọ awọn ènìyàn l'atari mimaa ba wọn lo pẹlu awọn iwa daada.
Iseni l'oju kòkòrò láti máa ṣe iṣẹ rere leyin àìdá, bẹẹni ìwà dáadáa wa nínú apẹrẹ ìbẹrù Ọlọhun, ṣugbọn wọn da oun nìkan yanri nítorípé a ní bukata sí ṣíṣe alaye rẹ.
Tira Sunanu ti Tirmidhiy (3/ 526) (1987).
Àlékún (7)
Tira Al-Arbaiinan-Nawawiyyah (Ogójì Hadith tí alfa àgbà An-nawawi ko jọ) (ص100) (ح18).
التحفة الربانية في شرح الأربعين حديثًا النووية.
لإسماعيل الأنصاري (ص40).
شرح الأربعين النووية.
لابن عثيمين (ص195).
فتح القوي المتين في شرح الأربعين وتتمة الخمسين.
لعبد المحسن البدر (ص67).
A tọ́ka sí nínú àwọn ìwé
15 Àwọn ÌwéÀlékún (15)
- العلم الواجب بدون فقه وبدون زيادات1عَنْ أَبِي ذَرٍّ جُنْدُبُ بْنِ جُنَادَةَ، وَأَبِي عَبْدِ الرَّحْمَنِ مُعَاذِ بْنِ جَبَلٍ -رَّضِي اللَّهُ عَنْهُمَا-، عَن الرَّسُولِ -صَلَّى اللَّهُ عَلَيْه وَسَلَّمَ- قَالَ: (اتَّقِ اللهَ حَيْثُمَا كُنْتَ، وَأَتْبِعِ السَّيِّئَةَ الْحَسَنَة
- رياض الصالحينرياض الصالحين مع فوائد وهدايات - 1 «اتَّقِ اللهَ حَيْثُمَا كُنْتَ، وَأتْبعِ السَّيئَةَ الْحَسَنَةَ تَمْحُهَا، وَخَالِقِ النَّاسَ بخُلُقٍ حَسَنٍ».
- شرح الأربعين النووية«اتَّقِ اللَّهَ حَيْثُمَا كُنْت، وَأَتْبِعِ السَّيِّئَةَ الْحَسَنَةَ تَمْحُهَا، وَخَالِقِ النَّاسَ بِخُلُقٍ حَسَنٍ».
- مجموعة زاد التربية الإسلامية (2)1«اتَّقِ الله حَيْثُمَا كُنْتَ، وأتبِعْ السيئةَ الحسنةَ تمحُها، وخالِقِ الناسَ بخُلُقٍ حَسَنٍ».
- مجموعة زاد الحديث(3)1«اتَّقِ الله حَيْثُمَا كُنْتَ، وَأَتْبِعِ السَّيِّئَةَ الحَسَنَةَ تَمْحُهَا، وَخَالِق النَّاسَ بِخُلُقٍ حَسَنٍ»
- مجموعة زاد الحديث(3)1(وَخَالِق النَّاسَ بِخُلُقٍ حَسَنٍ)
- مجموعة زاد الحديث(3)1«وَخَالِقِ النَّاسَ بِخُلُقٍ حَسَنٍ»
- مشروع منهاج زادكزادك معلم 2«وَخَالِقِ النَّاسَ بِخُلُقٍ حَسَنٍ»
- مشروع منهاج زادكزادك 2 طالب نهائي«اتَّقِ اللهَ حَيْثُمَا كُنْتَ، وَأَتْبِعِ السَّيِّئَةَ الحَسَنَةَ تَمْحُهَا، وَخَالِقِ النَّاسَ بِخُلُقٍ حَسَنٍ»
- نبراس طالب (1)1«اتَّقِ اللهَ حَيْثُمَا كُنْتَ، وَأَتْبِعِ السَّيِّئَةَ الحَسَنَةَ تَمْحُهَا، وَخَالِقِ النَّاسَ بِخُلُقٍ حَسَنٍ»
- نبراس طالب (2)نبراس طالب (2) عَنْ معاذ بن جبل رضي الله عنه قَالَ: قَالَ لِي رَسُولُ اللهِ صلى الله عليه وسلم: «اتَّقِ اللهَ حَيْثُمَا كُنْتَ، وَأَتْبِعِ السَّيِّئَةَ الْحَسَنَةَ تَمْحُهَا، وَخَالِقِ النَّاسَ بِخُلُقٍ حَسَنٍ»
- نبراس طالب (4)1«وَخَالِقِ النَّاسَ بِخُلُقٍ حَسَنٍ»
- نبراس طالب (5)1«اتَّقِ اللهَ حَيْثُمَا كُنْتَ، وَأَتْبِعِ السَّيِّئَةَ الْحَسَنَةَ تَمْحُهَا، وَخَالِقِ النَّاسَ بِخُلُقٍ حَسَنٍ»
- وثيقة منهج نبراس لمدارس نهاية الأسبوع1"اتق الله حيثما كنت، واتبع السيئة الحسنة تمحها، وخالق الناس بخلق حسن"
- وثيقة منهج نبراس لمدارس نهاية الأسبوع1"اتق الله حيثما كنت، واتبع السيئة الحسنة تمحها، وخالق الناس بخلق حسن"