Skip to content

Ti obinrin ba funra mọ ẹjẹ, ti ko jade ṣiwaju wiwọ oòrùn, tabi ki o ni ìmọ̀lára ìnira nǹkan oṣù, njẹ awẹ rẹ ọjọ yẹn ni alaafia, àbí idapada rẹ maa jẹ dandan fun un?

السؤال

Ibeere akọkọ:

Ti obinrin ba funra mọ ẹjẹ, ti ko jade ṣiwaju wiwọ oòrùn, tabi ki o ni ìmọ̀lára ìnira nǹkan oṣù, njẹ awẹ rẹ ọjọ yẹn ni alaafia, àbí idapada rẹ maa jẹ dandan fun un?

س8: إذا أحست المرأة بالدم، ولم يخرج قبل الغروب، أو أحست بألم العادة، فهل يصحّ صيامها ذلك اليوم، أو يجب عليها قضاؤه؟

الجواب

Idahun akọkọ:

Ti obinrin ti o mọ ba ni ìmọ̀lára pe ẹjẹ nnkan oṣu fẹ́ wá ti o si jẹ alaawẹ, ṣugbọn ko jade afi lẹyin wiwọ oòrùn, àbí ó ni ìmọ̀lára ìnira nǹkan oṣù, ṣùgbọ́n ko jade afi lẹyin wiwọ oòrùn, dajudaju awẹ rẹ ọjọ yẹn ni alaafia, ti idapada rẹ ko si jẹ dandan fun un ti o ba jẹ ọranyan, ti ẹsan rẹ ko si bajẹ pẹlu rẹ ti o ba jẹ aṣegbọrẹ.

ﺟ8: إذا أحست المرأة الطاهرة بانتقال الحيض وهي صائمةٌ، ولكنه لم يخرج إلا بعد غروب الشمس، أو أحست بألم الحيض، ولكنه لم يخرج إلا بعد غروب الشمس، فإن صومها ذلك اليوم صحيحٌ، وليس عليها إعادته إذا كان فرضًا، ولا يبطل الثواب به إذا كان نفلًا.