Nigba miiran obinrin maa n ri oripa kekere kan fun ẹjẹ tàbí ẹ̀kán ti o kéré gan ni àsìkò ọtọọtọ nínú ọjọ́ kan, nigba mii o le ri i ni asiko nnkan oṣu ti ko i tíì ṣan jade, nigba mii o le ri i ni asiko ti kii ṣe ti nǹkan oṣù, ki ni idajọ awẹ rẹ ni awọn iṣesi mejeeji naa?
السؤال
Ibeere akọkọ:

س10: أحيانًا ترى الـمرأة أثرًا يسيرًا للدم أو نقطًا قليلةً جدًّا متفرّقةً على ساعات اليوم، مرةً تراه وقت العادة وهي لم تنزل، ومرةً تراه في غير وقت العادة، فما حكم صيامها في كلتا الحالين؟
الجواب
Idahun akọkọ:
Idahun lori iru ibeere yii ti ṣaaju laipẹ yìí, ṣugbọn o ṣẹku pe ti o bajẹ pe awọn ẹ̀kán ẹ̀jẹ̀ yii wa ni awọn ọjọ nǹkan oṣù, yoo ka a si ara ẹjẹ nnkan oṣu ti o mọ ọn; torí pé ó máa jẹ ẹjẹ nnkan oṣu ni.
ﺟ10: سبق الجواب على مثل هذا السّؤال قريبًا، لكن بقي أنه إذا كانت هذه النّقط في أيام العادة، وهي تعتبره من الحيض الّذي تعرفه، فإنه يكون حيضًا.