"Ibeere ẹlẹẹkarundinlogun: Ki ni awọn majẹmu ironupiwada to ni alaafia? "
- الباب / الفصل
- قسم المنوعات
السؤال
س۱۸: ما شروط التوبة الصحيحة؟
"Ibeere ẹlẹẹkarundinlogun: Ki ni awọn majẹmu ironupiwada to ni alaafia? "
الجواب
ج:١. الإقلاع عن الذنب.
- الندم على ما فات.
- العزم على عدم العودة إليه.
- رد الحقوق والمظالم لأهلها.
- قال تَعَالَى:
﴿وَٱلَّذِينَ إِذَا فَعَلُواْ فَٰحِشَةً أَوۡ ظَلَمُوٓاْ أَنفُسَهُمۡ ذَكَرُواْ ٱللَّهَ فَٱسۡتَغۡفَرُواْ لِذُنُوبِهِمۡ وَمَن يَغۡفِرُ ٱلذُّنُوبَ إِلَّا ٱللَّهُ وَلَمۡ يُصِرُّواْ عَلَىٰ مَا فَعَلُواْ وَهُمۡ يَعۡلَمُونَ﴾
[آل عمران: ١٣٥].
"Idahun- 1- Jijawọ nibi ẹṣẹ. "
- Ṣiṣe abamọ lori nnkan to ti kọja.
"Ṣíṣe ipinnu lati ma pada si ibẹ mọ. "
"4- Dida awọn ẹtọ ati awọn nnkan ti wọn gba pẹ̀lú àbòsí pada fun awọn to ni i. "
Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe:
."{Àwọn tí (ó jẹ́ pé) nígbà tí wọ́n bá ṣe ìbàjẹ́ kan tàbí tí wọ́n bá ṣàbòsí sí ẹ̀mí ara wọn, wọ́n á rántí Allāhu, wọ́n á sì tọrọ àforíjìn fún ẹ̀ṣẹ̀ wọn, - Ta sì ni Ó ń forí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ jin (ẹ̀dá) bí kò ṣe Allāhu. Wọn kò sì takú sórí ohun tí wọ́n ṣe nígbà tí wọ́n mọ̀ (pé ẹ̀ṣẹ̀ ni) 135}. "
[Surah Âl-`Imrân: 19]"