Skip to content

Awọn wo ni awọn ti wọn fun un ni ọyàn ati awọn ti wọn tọju rẹ lẹyin iya rẹ.

الباب / الفصل
قسم السيرة النبوية

السؤال

س6: من مرضعاته وحواضنه غير أمه؟

Ibeere 6: Awọn wo ni awọn ti wọn fun un ni ọyàn ati awọn ti wọn tọju rẹ lẹyin iya rẹ.

الجواب

ج:- مولاة أبيه أم أيمن.

  • مولاة عمه أبي لهب، ثويبة.
  • حليمة السعدية.

Idahun- Ẹrubinrin ti baba rẹ sọ di ọmọluabi ti n jẹ Ummu Ayman.

  • Ẹrubinrin ti ọmọ-ìyá baba rẹ Abū Lahab sọ di ọmọluabi ti n jẹ Thuwaybah.
  • Halīmatu As-Sa‘diyyah.