Skip to content
Al-Hij'r /

Ẹsẹ 87

15 : 87

Ẹsẹ 87 of Al-Hij'r (15 : 87). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

Al-Hij'r Àwọn Ẹsẹ 99
Súrà · Al-Hij'r
Yorùbá · Mikail
15 : 87

وَلَقَدۡ ءَاتَيۡنَٰكَ سَبۡعٗا مِّنَ ٱلۡمَثَانِي وَٱلۡقُرۡءَانَ ٱلۡعَظِيمَ

Dájúdájú A fún ọ ní Sab‘u Mọthānī (ìyẹn, sūrah al-Fātihah) àti al-Ƙur’ān Ńlá.