Skip to content
النِّسَاء /

Ẹsẹ 158

4 : 158

Ẹsẹ 158 of النِّسَاء (4 : 158). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

النِّسَاء Àwọn Ẹsẹ 176
4 : 158

بَل رَّفَعَهُ ٱللَّهُ إِلَيۡهِۚ وَكَانَ ٱللَّهُ عَزِيزًا حَكِيمٗا

bí kò ṣe pé Allāhu gbé e wá sókè lọ́dọ̀ Rẹ̀ ni. Allāhu sì ń jẹ́ Alágbára, Ọlọ́gbọ́n.

Explanation & meanings · 1
  1. Āyah yìí kò túmọ̀ sí "ṣùgbọ́n A gbé e ga ní ipò" gẹ́gẹ́ bí àwọn kan ṣe lérò.