Skip to content
النَّحل /

Ẹsẹ 37

16 : 37

Ẹsẹ 37 of النَّحل (16 : 37). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

النَّحل Àwọn Ẹsẹ 128
Súrà · النَّحل
Yorùbá · Mikail
16 : 37

إِن تَحۡرِصۡ عَلَىٰ هُدَىٰهُمۡ فَإِنَّ ٱللَّهَ لَا يَهۡدِي مَن يُضِلُّۖ وَمَا لَهُم مِّن نَّٰصِرِينَ

Tí o bá ń ṣojú kòkòrò sí ìmọ̀nà wọn, dájúdájú Allāhu, ẹni tí Ó bá ṣì lọ́nà, kò níí mọ̀nà, kò sì níí sí àwọn alárànṣe kan kan fún wọn.

Explanation & meanings · 1
  1. Bákan náà ni ìtúmọ̀ gbólóhùn yìí àti tinú sūrah al-’A‘rọ̄f; 7:186.