Ti ẹni ti ẹjẹ ìbímọ ba n da lara rẹ ba mọ ṣiwaju ogoji ọjọ, njẹ hajj rẹ ni alaafia? Ti ko ba ri mimọ, ki ni yoo ṣe ti o si gbero ṣíṣe hajj?
السؤال
Ibeere akọkọ:
Ti ẹni ti ẹjẹ ìbímọ ba n da lara rẹ ba mọ ṣiwaju ogoji ọjọ, njẹ hajj rẹ ni alaafia? Ti ko ba ri mimọ, ki ni yoo ṣe ti o si gbero ṣíṣe hajj?
س60: إذا طهرت النّفساء قبل الأربعين فهل يصحّ حجّها؟ وإذا لم تر الطّهر فماذا تصنع، مع العلم أنها ناويةٌ الحج؟
الجواب
Idahun akọkọ:
Ti ẹni ti ẹjẹ ìbímọ ba n da lara rẹ ba mọ ṣiwaju ogoji ọjọ, yoo wẹ, yoo kirun, yoo si ṣe gbogbo nnkan ti awọn ti wọn mọ n ṣe, títí ti o fi dórí irọkirika ile Oluwa; nitori pe ẹjẹ ìbímọ ko si aala fun ọjọ ti o kere julọ fun un
Ṣugbọn ti ko ba ri mimọ, dajudaju hajj rẹ ni alaafia, ṣugbọn ko nii rọkirika ile Oluwa titi ti yoo fi mọ
Nitori pe Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- kọ fun ẹni ti o n ṣe nnkan oṣu kuro nibi irọkirika ile Oluwa, ati pe ẹjẹ ibimọ da gẹgẹ bii ẹjẹ nnkan oṣu nibi eyi
ﺟ60: إذا طهرت النّفساء قبل الأربعين فإنها تغتسل، وتصلّي، وتفعل كل ما تفعله الطاهرات حتى الطواف؛ لأن النّفاس لا حد لأقلّه.
أما إذا لم تر الطّهر فإن حجها صحيحٌ أيضًا، لكن لا تطوف بالبيت حتى تطهر؛ لأن النبي ﷺ منع الحائض من الطواف بالبيت[1]، والنّفاس مثل الحيض في هذا.
[29] تقدم تخريجه.