Skip to content

السؤال

Ibeere akọkọ:

Ti obinrin ba ri nnkan oṣu ni ọjọ Arafah, ki ni yoo ṣe?

س58: إذا حاضت المرأة يوم عرفة فماذا تصنع؟

الجواب

Idahun akọkọ:

Ti obinrin ba ri nnkan oṣu ni ọjọ, yoo tẹsiwaju nibi iṣẹ Hajj, yoo si ṣe nnkan ti awọn eniyan n ṣe, ko si nii rọkirika ile Oluwa titi ti yoo fi mọ́.

ﺟ58: إذا حاضت المرأة يوم عرفة فإنها تستمرّ في الحجّ، وتفعل ما يفعل الناس، ولا تطوف بالبيت حتى تطهر.