Skip to content

Ti obinrin ba ri nnkan oṣu lẹyin jiju oko jamratul akọba, ati ṣiwaju irọkirika ile Oluwa ti ifaadọ, ti oun ati ọkọ rẹ si so pọ mọ awọn arìnrìn-àjò kan ti wọn jọ n lọ papọ, ki ni o jẹ dandan fun un lati ṣe, ti o si mọ pe pipada ko lee rọrun fun oun lẹyin ìrìn-àjò rẹ?

السؤال

Ibeere akọkọ:

س59: إذا حاضت المرأة بعد رمي جمرة العقبة، وقبل طواف الإفاضة، وهي مرتبطةٌ هي وزوجها مع رفقةٍ، فماذا عليها أن تفعل، مع العلم أنه لا يمكنها العودة بعد سفرها؟

الجواب

Idahun akọkọ:

Ti pipada ko ba rọrun fun un, yoo we nǹkan mọ́ oju ara rẹ, lẹyin naa yoo rọkirika ile Oluwa fun làlúrí, ko si si ẹṣẹ kankan fun un, yoo si pari awọn iṣẹ hajj ti o ṣẹku

ﺟ59: إذا لم يمكنها العودة فإنها تتحفظ، ثم تطوف للضرورة، ولا شيء عليها، وتكمل بقية أعمال الحجّ.