Ki ni idajọ nǹkan ti o fẹ́ dudu ti o maa n jade latara obinrin ṣiwaju nnkan oṣu pẹ̀lú ọjọ kan tabi ju bẹẹ lọ tabi ti o kere si i, ti o ṣe pe nnkan ti o n jade da bíi owu tiirin dudu kan, tabi aláwọ̀ ilẹ̀ tabi nnkan ti o jọ iyẹn? Ki ni idajọ ti o ba jẹ lẹ́yìn nnkan oṣu?
السؤال
Ibeere akọkọ:

س46: ما حكم الكدرة الّتي تنزل من المرأة قبل الحيض بيومٍ أو أكثر أو أقل، وقد يكون النازل على شكل خيطٍ رقيقٍ أسود أو بنّيٍّ أو نحو ذلك؟ وما الحكم لو كانت بعد الحيض؟
الجواب
Idahun akọkọ:
Ti eyi ba wa ninu awọn nǹkan ti maa n ṣáájú nnkan oṣu, a jẹ wipe nnkan oṣu ni, wọn maa da iyẹn mọ pẹlu awọn irora ati inu rirun ti o maa n sáábà ṣẹlẹ̀ si ẹni ti o n ṣe nnkan oṣu
Ṣugbọn omi ti o fẹ dudu lẹyin nnkan oṣu, yoo ṣe suuru titi ti yoo fi lọ; nitori pe dudu ti o so pọ mọ nnkan oṣu, nnkan oṣu ni; fun ọrọ Aisha- ki Ọlọhun yọnu si i- pe: Ma kanju titi ti o fi maa ri omi funfun. Ọlọhun ni O ni imọ julọ
ﺟ46: هذه إذا كانت من مقدّمات الحيض فهي حيضٌ، ويعرف ذلك بالأوجاع والـمغص الّذي يأتي الحائض عادةً.
أمّا الكدرة بعد الحيض فتنتظر حتى تزول؛ لأن الكدرة المتصلة بالحيض حيضٌ؛ لقول عائشة رضي الله عنها:
«لَا تَعْجَلْنَ حَتَّى تَرَيْنَ الْقَصَّةَ الْبَيْضَاءَ»[1]
والله أعلم.
[17] تقدم تخريجه.
من أحكام الحيض في الحجّ والاعتمار