Skip to content

Awọn kan maa n sọ pe ẹ sọ pe ki èèyàn má ṣe aluwala latara nnkan ti n sàn naa?

السؤال

Ibeere akọkọ:

Awọn kan maa n sọ pe ẹ sọ pe ki èèyàn má ṣe aluwala latara nnkan ti n sàn naa?

س45: هناك من ينسب إليك القول بعدم الوضوء من ذلك السائل؟

الجواب

Idahun akọkọ:

Irọ́ ni ẹni tí n fi ọrọ yii ti si mi lọ́dọ̀ ń pa, eyi ti o han ni pe o gbọye nínú ọrọ mi pe: “Dajudaju o jẹ nnkan ti o mọ”, wi pe ko nii ba aluwala jẹ

ﺟ45: الّذي ينسب عنّي هذا القول غير صادقٍ، والظاهر أنه فهم من قولي: إنه طاهرٌ أنه لا ينقض الوضوء.