Ki ni idajọ kika Kuraani ẹni ti o n ṣe nnkan oṣu ati ẹni ti ẹjẹ ìbímọ n da lara rẹ ni ti wiwo ati hiha ni iṣesi kò-ṣeé-má-ṣe, bii ki o jẹ ọmọ akẹkọọ lobinrin tabi olukọ lobinrin?
السؤال
Ibeere akọkọ:
Ki ni idajọ kika Kuraani ẹni ti o n ṣe nnkan oṣu ati ẹni ti ẹjẹ ìbímọ n da lara rẹ ni ti wiwo ati hiha ni iṣesi kò-ṣeé-má-ṣe, bii ki o jẹ ọmọ akẹkọọ lobinrin tabi olukọ lobinrin?
س17: ما حكم قراءة الحائض والنّفساء للقرآن نظرًا وحفظًا في حال الضرورة، كأن تكون طالبةً أو معلّمةً؟
الجواب
Idahun akọkọ:
Ko si ẹṣẹ fun obinrin ti o n ṣe nnkan oṣu tabi ti ẹjẹ ìbímọ n da lara rẹ nibi kika Kuraani ti o ba bukaata si i, gẹgẹ bii olukọ lobinrin, tabi ki o jẹ akẹ́kọ̀ọ́ ti o n ka ìpín rẹ ti kò le má kà ni alẹ ati ọsan,
Ṣugbọn kika Kuraani lati wa ẹsan- eyi ti o daa julọ ni ki o ma ṣe e; nitori pe ọpọlọpọ ninu awọn onimimọ tabi eyi ti o pọ̀ jù nínú wọn ri pe ẹni ti o n ṣe nnkan oṣu, kika Kuraani ko lẹtọọ fun un
ﺟ17: لا حرج على المرأة الحائض أو النّفساء في قراءة القرآن إذا كان لحاجةٍ، كالمرأة المعلّمة، أو الدارسة الّتي تقرأ وردها في ليلٍ أو نهارٍ.
وأما القراءة -أعني: قراءة القرآن لطلب الأجر وثواب التّلاوة- فالأفضل ألا تفعل؛ لأن كثيرًا من أهل العلم أو أكثرهم يرون أن الحائض لا يحلّ لها قراءة القرآن.