Skip to content

"Ibeere ẹlẹẹkarundinlọgbọn: Ki ni nnkan ti wọn ṣe ni ọran-anyan le e lori ni Mẹdina ninu awọn ofin Isilaamu? "

الباب / الفصل
قسم السيرة النبوية

السؤال

س25: ماذا فرض عليه في المدينة من شرائع الإسلام؟

"Ibeere ẹlẹẹkarundinlọgbọn: Ki ni nnkan ti wọn ṣe ni ọran-anyan le e lori ni Mẹdina ninu awọn ofin Isilaamu? "

الجواب

ج:فرض عليه الزكاة، والصيام، والحج، والجهاد، والأذان، وغيرها من شرائع الإسلام.

"Idahun- wọn ṣe yiyọ zakah ni ọranyan le e lori, ati aawẹ gbigba, ati lilọ si ile oluwa, ati jijagun si oju-ọna Ọlọhun, ati pipe irun, ati eyi to yatọ si i ninu awọn ofin Isilaamu.