Skip to content
الأحزَاب /

Ẹsẹ 34

33 : 34
الأحزَاب Àwọn Ẹsẹ 73
Súrà · الأحزَاب
Yorùbá · Mikail
33 : 34

وَٱذۡكُرۡنَ مَا يُتۡلَىٰ فِي بُيُوتِكُنَّ مِنۡ ءَايَٰتِ ٱللَّهِ وَٱلۡحِكۡمَةِۚ إِنَّ ٱللَّهَ كَانَ لَطِيفًا خَبِيرًا

Ẹ rántí ohun tí wọ́n ń ké nínú ilé yín nínú àwọn āyah Allāhu àti ìjìnlẹ̀ òye (ìyẹn, sunnah Ànábì - kí ìkẹ́ àti ọlà Allāhu máa bá a -). Dájúdájú Allāhu ń jẹ́ Aláàánú, Onímọ̀-ìkọ̀kọ̀.

Explanation & meanings · 1
  1. Āyah yìí ti fi hàn pé ẹ̀sìn fẹ́ kí àwọn mùsùlùmí lóbìnrin máa jósìn nínú ilé wọn.