Skip to content
البَقَرَة /

Ẹsẹ 10

2 : 10

Ẹsẹ 10 of البَقَرَة (2 : 10). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

البَقَرَة Àwọn Ẹsẹ 286
2 : 10

فِي قُلُوبِهِم مَّرَضٞ فَزَادَهُمُ ٱللَّهُ مَرَضٗاۖ وَلَهُمۡ عَذَابٌ أَلِيمُۢ بِمَا كَانُواْ يَكۡذِبُونَ

Àrùn kan wà nínú ọkàn wọn, nítorí náà Allāhu ṣe àlékún àrùn (náà) fún wọn. Ìyà ẹlẹ́ta-eléro sì wà fún wọn nítorí pé wọ́n ń parọ́.

Explanation & meanings · 1
  1. Àrùn iyèméjì àti ìṣojúméjì sí āyah al-Ƙur’ān.