Skip to content
النَّحل /

Ẹsẹ 118

16 : 118
النَّحل Àwọn Ẹsẹ 128
Súrà · النَّحل
Yorùbá · Mikail
16 : 118

وَعَلَى ٱلَّذِينَ هَادُواْ حَرَّمۡنَا مَا قَصَصۡنَا عَلَيۡكَ مِن قَبۡلُۖ وَمَا ظَلَمۡنَٰهُمۡ وَلَٰكِن كَانُوٓاْ أَنفُسَهُمۡ يَظۡلِمُونَ

Àti pé A ṣe ohun tí A sọ fún ọ ṣíwájú ní èèwọ̀ fún àwọn tó di yẹhudi. A kò sì ṣàbòsí sí wọn, ṣùgbọ́n àwọn ni wọ́n n ṣàbòsí sí ẹ̀mí ara wọn.

Explanation & meanings · 1
  1. Ìyẹn nínú sūrah an-Nisā’; 4:160 - 161.