Skip to content
الحِجر /

Ẹsẹ 48

15 : 48

Ẹsẹ 48 of الحِجر (15 : 48). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

الحِجر Àwọn Ẹsẹ 99
Súrà · الحِجر
Yorùbá · Mikail
15 : 48

لَا يَمَسُّهُمۡ فِيهَا نَصَبٞ وَمَا هُم مِّنۡهَا بِمُخۡرَجِينَ

Wàhálà kan kò níí bá wọn nínú rẹ̀. Wọn kò sì níí mú wọn jáde kúrò nínú rẹ̀.