Skip to content

Ẹni ti ko ba kii ṣe aluwala ninu awọn obinrin; latari aimọkan rẹ nipa idajọ naa, ki ni o jẹ dandan fun un lati ṣe?

السؤال

Ibeere akọkọ:

Ẹni ti ko ba kii ṣe aluwala ninu awọn obinrin; latari aimọkan rẹ nipa idajọ naa, ki ni o jẹ dandan fun un lati ṣe?

س44: من كانت من النّساء لا تتوضأ؛ لجهلها بالحكم، ماذا عليها؟

الجواب

Idahun akọkọ:

O jẹ dandan fun un lati ronupiwada lọ si ọdọ Ọlọhun- Alagbara ti O gbọnngbọn-, ki o si beere nipa ìyẹn lọdọ awọn onimimọ

ﺟ44: عليها أن تتوب إلى الله عز وجل، وتسأل أهل العلم بذلك.