Skip to content

Ti obìnrin ti nnkan ti n san n jade lara rẹ lai dúró fun irun ọran-anyan, njẹ o tọna fun un lati ki nnkan ti o ba fẹ ninu awọn nafila tabi ki o ka Kuraani pẹlu aluwala ọran-anyan yẹn titi di akoko ọran-anyan keji?

السؤال

Ibeere akọkọ:

س36: إذا توضأت المرأة التي ينزل منها السائل مستمرًّا لصلاة فرضٍ، فهل يصحّ لها أن تصلّي ما شاءت من النوافل أو قراءة القرآن بوضوء ذلك الفرض إلى حين الفرض الثاني؟

الجواب

Idahun akọkọ:

Ti o ba ṣe aluwala fun irun ọran-anyan lati ìbẹ̀rẹ̀ akoko, o lẹ́tọ̀ọ́ fun un lati ki nnkan ti o fẹ ninu awọn ọran-anyan ati awọn nafila ati kika Kuraani titi ti akoko irun miiran yoo fi wọle

ﺟ36: إذا توضأت لصلاة الفريضة من أول الوقت فلها أن تصلّي ما شاءت من فروضٍ ونوافل وقراءة قرآنٍ إلى أن يدخل وقت الصلاة الأخرى.