Skip to content

Njẹ o tọna fun obinrin yẹn lati ki irun duha pẹlu aluwala alufajari?

السؤال

Ibeere akọkọ:

Njẹ o tọna fun obinrin yẹn lati ki irun duha pẹlu aluwala alufajari?

س37: هل يصحّ أن تصلّي تلك المرأة صلاة الضّحى بوضوء الفجر؟

الجواب

Idahun akọkọ:

Iyẹn ko tọna; nitori pe irun duha jẹ nnkan ti o ni akoko, o jẹ dandan ki o ṣe aluwala fun un lẹyin wiwọle akoko rẹ; nitori pe eleyii da gẹgẹ bii ẹni ti ẹjẹ awaada n da lara rẹ, Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- si ti pa ẹni ti ẹjẹ awaada n da lara rẹ laṣẹ lati maa ṣe aluwala fun gbogbo irun kọ̀ọ̀kan

Akoko Zuhr ni: Lati igba ti orun ba ti yẹ atari titi di akoko Asr

Akoko Asr: Lati igba ti akoko Zuhr ba ti lọ titi di akoko ti oorun maa di aláwọ̀ ìyeyè, ati pe akoko làlúrí rẹ ni titi di wiwọ oòrùn.

Akoko Magrib: Lati akoko wiwọ oòrùn titi ti awonpapa pupa yóò fi wọlé.

Akoko Ishai: Lati wiwọle awonpapa pupa titi di idaji oru

ﺟ37: لا يصح ذلك؛ لأن صلاة الضّحى مؤقتةٌ، فلابد من الوضوء لها بعد دخول وقتها؛ لأن هذه كالمستحاضة، وقد أمر النبيّ ﷺ المستحاضة أن تتوضأ لكلّ صلاةٍ.

ووقت الظّهر: من زوال الشمس إلى وقت العصر.

ووقت العصر: من خروج وقت الظّهر إلى اصفرار الشمس، والضرورة إلى غروب الشمس.

ووقت المغرب: من غروب الشمس إلى مغيب الشفق الأحمر.

ووقت العشاء: من مغيب الشفق الأحمر إلى نصف الليل.